Robert Menzies
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Australia
Robert Gordon Menzies je oloselu omo ile Australia ni Menzies. A bi i ni 1894. O je olootu ijoba ile Australia fun odun mokandinlogun. Ilu Jepart ni won ti bi i ni Victoria. O gba oye ninu ofin ni University Melborne. Ni aarin 1928 si 1934, o wa ni Victoria State Legislature. Nigba ti o se, o wo federal House of Representative. O di Attorney General ile Australia ni aarin 1935 si 1939. Leyin igba ti J. A. Lyons ku ni Menzies wa di olootu Australia. O fi ori oye sile funraare ni 1966.
Sir Robert Gordon Menzies | |
---|---|
12th Prime Minister of Australia Elections: 1940, 1946—1963 | |
In office 26 April 1939 – 26 August 1941 | |
Asíwájú | Earle Page |
Arọ́pò | Arthur Fadden |
In office 19 December 1949 – 26 January 1966 | |
Asíwájú | Ben Chifley |
Arọ́pò | Harold Holt |
Constituency | Kooyong (Victoria) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Jeparit, Victoria | 20 Oṣù Kejìlá 1894
Aláìsí | 15 May 1978 Melbourne, Victoria | (ọmọ ọdún 83)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United Australia; Liberal |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Pattie Leckie |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |