Roger Hallam (olugboja)
Julian Roger Hallam [citation needed]) (tí a bí ní ọdún 1965/1966 ) [citation needed]) jẹ́ ajàfitafita àyíká tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ Extinction Rebellion , [1] [2] Just Stop Oil, [3] Insulate Britain, [4] àjọ ẹgbẹ́ Àjùmọ̀se Radical. Routes , [5] ati ẹgbẹ́ òṣèlú Burning Pink . [6] Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2024, Hallam gba ìdá dúró fún ọdún méjì fún ìgbìyànjú láti dènà pápá ọkọ̀ òfurufú Heathrow pẹ̀lú dírọ́ọ̀nù. Ní Oṣù Keje ọdún 2024, Hallam jẹ̀bi ẹ̀sùn ti rìkísí láti dá ìrúkèrúdò àwùjọ sílẹ̀ fún sí ṣètò ìfẹ̀hónúhàn láti dínà opopona M25 ní ọdún méjì sẹ́yìn, fún èyí tí ó lọ sí ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún.[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Leake, Jonathan (25 November 2018). "Meet Dr Demo, the activist behind the road-block radicals". https://www.thetimes.co.uk/article/meet-dr-demo-the-activist-behind-the-road-block-radicals-nzd6dsp5k. Retrieved 30 June 2019.
- ↑ Knight, Sam (21 July 2019). "Does Extinction Rebellion Have the Solution to the Climate Crisis?". https://www.newyorker.com/news/letter-from-the-uk/does-extinction-rebellion-have-the-solution-to-the-climate-crisis. Retrieved 22 September 2019.
- ↑ Gayle, Damien (18 October 2023). "Greta Thunberg charged with public order offence after London oil protest". London, United Kingdom. https://www.theguardian.com/uk-news/2023/oct/18/greta-thunberg-charged-with-public-order-offence-after-london-oil-protest. Retrieved 18 October 2023.
- ↑ Dracott, Edd (24 June 2022). "Climate protesters will block roads 'day after day' in October, says XR founder". https://www.standard.co.uk/news/uk/roger-hallam-government-just-stop-oil-london-insulate-britain-b1008307.html.
- ↑ Albery, Nicholas (1992) (in en). The Book of Visions: An Encyclopaedia of Social Innovations. Virgin. ISBN 9780863696015. https://books.google.com/books?id=HN_wAAAAMAAJ. Retrieved 25 March 2019.
- ↑ Taylor, Diane (25 June 2020). "Extinction Rebellion activists launch UK Beyond Politics party by stealing food" (in en). https://www.theguardian.com/environment/2020/jun/25/uk-extinction-rebellion-activists-launch-beyond-politics-party-by-stealing-food. Retrieved 27 August 2020.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedBBC18July2024