Ronald Chagoury (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kìíní ọdún 1949) jẹ́ oníṣòwò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Chagoury Group pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, Gilbert Chagoury.

Ìgbésíayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Ronald Chagoury sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù kìíní, ọdún 1949. Ó sì jẹ́ ọmọ Ramez àti Alice Chagoury tí ó kúrò ní ìlú Lebanon ní ọdún 1940. Ó kàwé ní College des Frères Chrétiens ní ìlú Lebanon, ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ nípa òwò ní California State University, tí ó wà ní Long Beach, ní US.[1]

Chagoury fẹ́ Berthe, wọ́n bí ní ọmọ méjì papọ̀.[1]

Chagoury ti yọ nínú ìwé Panama.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Executive Team". Chagoury Group. Archived from the original on 2016-05-22. Retrieved 2016-05-20. 
  2. Leaf, Aaron. "Nigeria's Chagoury Group Named In Latest Panama Papers Revelation Okayafrica". Okayafrica.com. Retrieved 2016-05-20.