Ronald Chagoury (Oníṣòwò)
Ronald Chagoury (ọjọ ìbí Jésù ọjọ kẹjọ, oṣù kínní ọdún 1949) jẹ́ Oníṣòwò kàn ní orílé èdè Nàìjíríà, òun àti àbúrò rẹ̀ Gilbert Chagoury ní wọn jọ dá ilé iṣé Chagoury Groupb sílẹ, wọn sì jọ jẹ Olùdarí àti Olúdàsìlè.
Ronald Chagoury | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kínní 1949 Benin City, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | College des Frères Chrétiens des Écoles Chrétiennes |
Iléẹ̀kọ́ gíga | California State University, Long Beach |
Iṣẹ́ | CEO, Chagoury Group |
Parent(s) | Ramez and Alice Chagoury |
Àwọn olùbátan | Gilbert Chagoury (brother) |
Ìgbé Ayé
àtúnṣeWọn bí Ronald Chagoury sí orílè èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kínní ọdún 1949, tí ó jẹ́ ọmọ Ramez àti Alice Chagoury, tí wọ́n dì jọ kúrò ní Lebanon ní ọdún 1949. Ó kàwé ní College des Frères Chrétiens ní Lebanon, bákan náà ní ọ kàwé gbọye nínú èkó ìṣirò ni Fásitì ti ó wà California ní Long Beach ní orílé èdè Améríkà.[1]
Chagoury ṣe ìgbéyàwó pẹlu Berthe, wọn sì jọ́ bímọ méjì.[1]
Orúkọ Chagoury'l tí jáde nínú ìwé ìròyìn Panama.[2]
Àwọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Executive Team". Chagoury Group. Archived from the original on 2016-05-22. Retrieved 2016-05-20.
- ↑ Leaf, Aaron. "Nigeria's Chagoury Group Named In Latest Panama Papers Revelation Okayafrica". Okayafrica.com. Retrieved 2016-05-20.