Ronke Ojo
Ronke Ojo tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje ọdún 1974 (July 17, 1974)tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Rónkẹ́ Òṣòdì-Òkè jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]Bákan náà, Rónkẹ́ jẹ́ akọrin
Ronke Ojo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Keje 1974 Oworoshonki, Kosofe, Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1998–present |
Olólùfẹ́ | Anthony Gbolahan (m. 2009) |
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́
àtúnṣeRónkẹ́ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Oǹdó, ṣùgbọ́n ìpínlẹ̀ Èkó, ní ìlú Òwòròǹṣòkí ni ó ti ṣe kékeré dàgbà.[2][3] [4] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà pẹ̀lú ẹgbẹ́ òṣèré tíátà kan tí wọ́n ń pè Star Parade tí Fádèyí Olóró jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀. Ìràwọ̀ Rónkẹ́ kò tètè tàn àfi lọ́dún 2000 tí ó gbé sinimá àgbéléwò kan jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Òṣòdì-Òké.[5][6] Lọ́dún 2014, ó kán ságbo orin.[7][8] In 2015, she released a single titled Ori Mi which featured 9ice.[9]
Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀
àtúnṣe- Succubus (2014)
- Asán Layé
- Eèsù
- Agbèrè Ojú
- Return of Jenifa
- Abeke Aleko
- Abeke Eleko 2
- Ajílodà
- Àìmàsìkò Ẹ̀dá (2006)
- Okùn Ìfẹ́ 2 (2004)
- Okùn Ìfẹ́ (2004)
- Àṣírí (2002)
- Òṣòdì Òkè (2000)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Top Nollywood Actress, Ronke Oshodi-Oke in a recent interview with Vanguard revealed that her big boobs brought her into limelight". Naij. Archived from the original on December 10, 2015. Retrieved December 12, 2014.
- ↑ "Ronke Ojo". iroktv.com. Archived from the original on 2019-12-25. Retrieved 2019-12-25.
- ↑ Adams Odunayo (8 October 2014). "Actress Ronke Oshodi Reveals Her Greatest Regret". Naij.com - Nigeria news. Retrieved 5 December 2015.
- ↑ "YORUBA ACTRESS,RONKE OSHODI OKE WEDS SYLVESTER OMOGBOLAHAN IN NIGERIA". Nigeria Films. February 3, 2009. http://www.modernghana.com/movie/3885/3/yoruba-actressronke-oshodi-oke-weds-sylvester-omog.html.
- ↑ "My boobs brought me to limelight—— Ronke Ojo". Vanguard News. 26 October 2014. Retrieved 5 December 2015.
- ↑ Ayo Onikoyi. "My boobs brought me to limelight—— Ronke Ojo". Vanguard Nigeria. http://www.vanguardngr.com/2014/10/my-boobs-brought-me-to-limelight-ronke-ojo/. Retrieved October 26, 2014.
- ↑ Esho Wemimo (24 November 2014). "Ronke Oshodi-Oke: Actress drops new album". pulse.ng. Archived from the original on 8 December 2015. Retrieved 5 December 2015.
- ↑ ""Why I won't release my album yet" – Ronke Oshodi-Oke". Pulse NG. April 7, 2015. Archived from the original on March 4, 2016. Retrieved December 25, 2019.
- ↑ Jimmy King (April 7, 2015). "Ronke Oshodi Oke – "Ori Mi" ft. 9ice (Prod. by ID Cabasa)". tooXclusive. http://tooxclusive.com/downloadmp3/ronke-oshodi-oke-ori-mi-ft-9ice-prod-by-id-cabasa//.