Rose Aboaje (tí wọ́n bí ní ọdún 1977) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà, tó sì fìgbà kan jẹ́ eléré-ìdárayá tó máa ń sáré fún Nàìjíríà nínú àwọn ìdíje àárín ìlú àti ti àgbáyé. Ó ti gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ oníde àti onífàdákà nínú ìdíje ọgọ́rùn-ún mítà (100) àti igba (200) mítà níbi ayẹyẹ 1998 African Championships in Athletics.[1][2]

Rose Aboaje
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ àbísọRose Aboaje
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí1977
Nigeria
Height163 cm
Weight58 kg
Sport
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà Nàìjíríà
Erẹ́ìdárayáAthletics
Event(s)100 metres, 200 metres

Ìdíje àgbáyé

àtúnṣe
Aṣojú   Nàìjíríà
1998 African Championships Dakar, Senegal 3rd 100 m 11.31
2nd 200 m 22.83
World Cup Johannesburg, South Africa 4th 4 × 100 m 42.91
1999 All-Africa Games Johannesburg, South Africa 5th (sf) 200 m 23.73

Ìkópa rẹ̀ nínú ìdíje tó pegedé

àtúnṣe
  • Ọgọ́rùn-ún mítà – 11.31 (1998)
  • Igba mítà – 22.83 (1998)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "IAAF Athletes Identity". IAAF Athletics Organisation. Retrieved 20 May 2020. 
  2. "African Championships Results". GBR Athletics. Archived from the original on 22 February 2020. Retrieved 20 May 2020.