Rose Odika jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò àti oníṣòwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Delta lorílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lọ́dún 1988. Ó ti tó ọgbọ̀n (30) tí ó ti ń ṣiṣẹ́ sinimá-àgbéléwò lédè Yorùbá. Òun ni Gómìnà ẹgbẹ́ tíátà tí wọ́n ń pè ní Theater Arts and Motion Pictures Practitioners Association of Nigeria (TAMPAN) tí èka ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.[2]

Rose Odika
Ọjọ́ìbíÌbàdàn
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́òṣèré
Ìgbà iṣẹ́1988-till date


Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Rose Odika Biography - MyBioHub". MyBioHub. 2017-07-07. Retrieved 2020-02-07. 
  2. "It took me 7 years after marriage to have a baby —Actress, Rose Odika » Kleiglight » Tribune Online". Tribune Online. 2020-01-11. Retrieved 2020-02-07.