Roseline Òṣípìtàn

Oloorì Roseline Omolará Osípìtàn jẹ́ ọmọọba ilé Yorùbá, ó sí tún jẹ́ Oníṣòwò orílé èdè Nàìjíríà. Ọ tí jẹ Ààrẹ àti Aláàga rí fún ilé iṣé Independent Petroleum Marketers Association ti Egbé àwọn obìnrin, ó sí jẹ́ Olùdásílẹ̀ Ilé iṣé Royal Oil and Gas. Òun náà sini Yèyé Ọba fún ìlú Ìtòrì.

Roseline Òṣípìtàn

Ìtàn ìgbé Ayé

àtúnṣe

Oloorì Roseline Osípìtàn jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Òndó ní orílé èdè Nàìjíríà. Osípìtàn sí ń ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí Oníṣòwò àgbà fún ilé iṣé epo-rọ̀bì kàn ní orílé èdè Nàìjíríà, níbi tí ó tí jẹ́ ọkan lára àwọn Obìnrin Adarí.[1][2] Osípìtàn ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ àti Aláàga fún IPMAN tí Egbé àwọn obìnrin, èyí tí o dá gẹ́gẹ́ bí òdì Kejì fún Egbe IPMAN tí orílé èdè Nàìjíríà.[3] Ospitian jẹ́ ẹni tí ó dá ilé iṣé First Royal Oil and Gas sile.[4]Ó sí jẹ́ àyà fún Ọmọoba Bọ́lá Osípìtàn àti Yèyé Ọba tí ìlú Ìtòrì.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Roseline Osipitan shines on - The Nation". Latestnigeriannews.com. Retrieved 2018-12-09. 
  2. "Omolara Osipitan puts best foot forward". Africanewshub.com. Archived from the original on 2023-04-05. Retrieved 2022-08-17. 
  3. Audu, Adetutu (30 November 2014). "Roseline Osipitan shines on". The Nation Nigeria. Retrieved 9 December 2018. 
  4. 4.0 4.1 "The Senator Ajibola and Princess Rose Osipitan Children’s nuptial people are dying to read on this blog + Groom’s Dad is a 4th term Senator and Bride’s mum an oil baroness …How Sweet Sensation joined them together". Asabeafrioka.com. Archived from the original on 2018-08-27. Retrieved 2022-08-17. 

Àdàkọ:Authority control