Rosemary Aluoch
Rosemary Aluoch jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kenya ti a bini 7, óṣu may ni ọdun 1976. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper ti o si ku si ilu Kasarani ni ọjọ kẹrin, óṣu october ọdun 2020[1][2].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 7 May 1976 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Dandora, Kenya | ||
Ọjọ́ aláìsí | 4 October 2020 | (ọmọ ọdún 44)||
Ibi ọjọ́aláìsí | Kasarani, Kenya | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1993–1995 | Makongeni Youth FC | ||
1996 | Eastlanders FC | ||
1997 | Chipeta Ladies | ||
1998–2001 | Minicus FC | ||
2002 | Old is Gold FC | ||
2003 | Kampala Capital City Authority FC | ||
2004–2005 | OC Bukavu Dawa | ||
2006–2007 | Lakolombe FC | ||
2008–2010 | Old is Gold FC | ||
2011–2012 | MOYAS FC | ||
2013 | Bukabu Dawa | ||
National team | |||
1995–2014 | Kenya women's national football team | 8 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣeRosemary ṣere fun team awọn obinrin ilẹ kenya lati 1995 si 2014, ni ọdun 2015, agbabọọlu naa di ọkan lara awọ̀n staff gẹgẹbi coach goalkeeper[3].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Harambee Starlets kit manager Rosemary Aluoch laid to rest". Football Kenya Federation. 2020-10-24. Retrieved 2022-06-16.
- ↑ "Rosemary “Maradona” Aluoch: A Fearless and passionate keeper". The Star. 2020-10-09. Retrieved 2022-06-16.
- ↑ Joshua, Elvince (2018-03-01). "Six former Harambee Stars goalkeepers complete course". Goal.com. Retrieved 2022-06-16.