Rotimi Salami (Yo-Rotimi Salami.ogg listen) jẹ́ òṣèrékùnrin àti olùṣàgbéjáde fíìmù tó ti fìgbà kan gba àmì-ẹ̀yẹ Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA).[1][2][3]

Rotimi Salami
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Ẹ̀kọ́Lagos State University, New York Film Academy
Ìgbà iṣẹ́2007—present
Olólùfẹ́Jumoke Salami
AwardsAfrica Magic Viewers' Choice Awards

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti Lagos State University, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa sociology. Ó gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ ni New York Film Academy.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ọdún 2007, níbi tí ó ti ṣe ìfarahàn rẹ̀ àkọ́kọ́ nínú fíìmù Unknown Revenge, lẹ́yìn náà ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán. Fíìmù rẹ̀ àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí i olùdarí eré ni Kuti's career Palace.[5]

Ìgbésí ayé ara ẹni

àtúnṣe

Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Jumoke Salami ní ọdún 2015, wọ́n sì jọ bí ọmọ méjì.[6][5][7]

Àtọ̀jọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bí i Tinsel, Superstory, Silent Night, About to Wed, Dear Mother, Kuti's Career Palace, Emerald, Alan Poza, Bella's Place, Leave My Boyfriend, 11th Hour, Papa Ajasco, Crack in the Wall;[8] àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn fíìmù mìíràn tí ó ti kópa nínú ni:

  • Omoye (2017) bíi Femi
  • Shadow Parties (2021) bíi Akinola
  • Just Not Married (2016) bíi Lati
  • Mirage (2019)
  • Divorce Not Allowed (2018) bíi Joe
  • Fate of Alakada (2020) bíi Lucky Accessbet
  • The Lost Heir (2018)
  • Diary of a Crazy Nigerian Woman (2017) bíi Chibuzor
  • More Than Just Four Letters (2020)
  • Timeless (2017)
  • African Queen (2018)
  • Unbroken (2018)
  • Lugard (2021) bíi Usman
  • Stormy Hearts (2017)
  • The Miracle Center (2021)
  • The Oap (2017)
  • Mentally (2017) bíi Udi
  • Rancor (2016)
  • Enemy Within (1994)
  • A Night Before (2015)
  • Hey You (2022) bíi Lanre

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Online, Tribune (11 June 2022). "My AMVCA outfit gave me the publicity I wanted —Rotimi Salami". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 July 2022. 
  2. "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Why I don't lie to women –Nollywood actor, Rotimi Salami". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 4 June 2022. Retrieved 20 July 2022. 
  4. "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. 5.0 5.1 "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  6. "Actor Rotimi Salami, wife celebrate 7th wedding anniversary - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 16 July 2022. 
  7. "My marriage... with actor Rotimi Salami". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 May 2022. Retrieved 16 July 2022. 
  8. "Spotlight Is On The 'Fresh Prince' Of Nollywood, Rotimi Salami". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 June 2018. Retrieved 16 July 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]