Roza Otunbayeva
Roza Isakovna Otunbayeva (Àdàkọ:Lang-ky, Rọ́síà: Роза Исаковна Отунбаева; ọjọ́ ibi August 23, 1950) ni Aare orílẹ̀èdè Kyrgyzstan. Wọ́n búra fún un ní July 3, 2010, lẹ́yìn tó ti dípò bí i olórí fún ìgbà díẹ̀ lẹ́yìn ijidide April 2010 tó fa lílé kúrò Ààrẹ Kurmanbek Bakiyev lórí ipò. Otunbayeva jẹ Alákóso ọ̀rọ̀ òkèrè tẹ́lẹ̀ àti olórí ìpàdé ilé aṣòfin fún Ẹgbẹ́ Tòṣèlú aráàlú Àwùjọ ilẹ̀ Kyrgyzstan. Roza Isakovna Otunbayeva jẹ́ ẹni pàtàkì nínú ìṣèlú orílẹ̀-èdè Kyrgyzstan, tí a mọ̀ fún ipa pàtàkì rẹ̀ nínú mímú ìlú náà ni ṣẹ nípasẹ̀ àkókò ìsọdọ̀tun ìṣèlú. Otunbayeva ni obìnrin àkọ́kọ́ tí yíò jẹ Ààrẹ orílẹ̀-èdè ọmọ ẹgbẹ́ CIS/SCO. Bákan náà, ó ti jẹ́ Ajàfẹ́tọ̀ó àwọn obìnrin, tí ó sì ti kó àwọn ipa takuntakun nínú ètò láti gbé ẹ̀kọ́, àwùjọ ìlú, àti ìjàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn síwájú si ní Ìlà Oòrùn Àárín ti Asia.
Roza Otunbayeva Роза Отунбаева | |
---|---|
President of Kyrgyzstan | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 3 July 2010 | |
Asíwájú | Kurmanbek Bakiyev |
Prime Minister of Kyrgyzstan Acting | |
In office 7 April 2010 – 19 May 2010 | |
Asíwájú | Daniar Usenov |
Arọ́pò | Vacant |
Minister of Foreign Affairs | |
In office 1992–1992 | |
Ààrẹ | Askar Akayev |
Alákóso Àgbà | Tursunbek Chyngyshev |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kẹjọ 1950 Osh, Soviet Union (now Kyrgyzstan) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Social Democratic Party |
Alma mater | Lomonosov Moscow State University |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |