Rufus Ada-George

Olóṣèlú

Rufus Ada-George je omo orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Rivers tele.