Ruth Osime
Ruth Osime (tí a bí ní ọjọ́ keje osù kejì ọdún 1964) jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ́-èdè Nàìjíríà.[1] ó ti figba kan jẹ́ olóòtú ìwe THISDAY Style Magazine ri, ti o jẹ́ ìwé ìròyìn tí ó ní se pẹ̀lú oge síṣe.[2][3]
Ruth Osime | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kejì 1964 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Journalist, Editor |
Parent(s) | Chief Grace Osime (Mother) |
Àwọn olùbátan | Grace Osime, Omome Osime-Oloyede |
Website | ThisDay Style |
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeRuth Osime ni ọmọ Chief Grace Osime, o si ni awọn àbúrò obìnrin méjì; Grace Osime àti Omome Osime-Oloyede.[4]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeIsẹ́ ẹ Osime ní ilé-isẹ́ THISDAY bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí ètò ilé-isẹ́ náà, léyìn náà ló di ònkọ̀wé ati olóòtú àrà ní odún 2003, ipò tí ó dìmú títí di osù kẹrin ọdún 2022.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Yaakugh, Kumashe (2021-03-10). "Who we offend? - Nigerian journalist reacts to 1976 receipt of N3,205 Honda car". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-25.
- ↑ Elites, The (2019-02-07). "Celebrating Ruth Osime, The Ultimate Style Connoisseur, At 55". The Elites Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-02.
- ↑ "Ruth Osime sets Lagos aglow". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-02-24. Retrieved 2021-12-02.
- ↑ Elites, The (2019-02-07). "Celebrating Ruth Osime, The Ultimate Style Connoisseur, At 55". The Elites Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-02.
- ↑ "About Us". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-02-26. Retrieved 2021-12-02.