Ruti Aga
Ruti Aga ni a bini ọjọ kẹrin dinlogun, óṣu January ni ọdun 1994 jẹ elere sisa ti ọna jinjin ti órilẹ ede Ethiopia. Ruti yege ninu ere awọn óbinrin ti ọdun 2019 ninu Marathon ti ilẹ Tokyo[1][2][3].
Ruti Aga – Tokyo Marathon (2019) | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ethiopian | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kínní 1994 | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Sport | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Sport of athletics | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Event(s) | Marathon, Half marathon | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Turned pro | 2016 | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeNi ọdun 2012, Aga gba ami ẹ̀yẹ ti silver ninu idije agbaye ti junior ere sisa to waye ni Barcelona, Spain. Ni ọdun 2013, Arabinrin pari pẹlu ipo karun ninu idije ere sisa ti awọn óbinrin ti IAAF agbaye cross country to waye ni Bydgoszcz, Poland. Ni ọdun 2019, Aga kopa ninu idije ere sisa agbaye ayẹyẹ marathon ti awọn obinrin[4]. Ni ọdun 2022, Ruti kopa ninu Marathon ti Chicago ninu ere sisa fun Wakati 2:21:41[5].