Sámúẹ́lì Johnson (ọmọ Yorùbá)

Samuel Johnson (24 June 1846 - 29 April 1901) je alufa ijo Anglikani omo Yoruba ti o ko itan Yoruba pelu akole A History of the Yorubas from the Earliest Times to the Beginning of the British Protectorate ti won tejade ni odun 1921 leyin iku re.


ItokasiÀtúnṣe