Samuel Odulana Odugade I
Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Sámúẹ́lì Odulana Odugade I)
Oba Samuel Odulana Odugade I (ojoibi 20 October, 1920) ni Olubadan ogoji lowolowo ni ilu Ibadan. O gun ori ite ni 2007. O ropo Oba Yunusa Ogundipe, Arapasowu 1.
Samuel Odulana Odugade I | |
---|---|
Coronation | 7 Osu Karun, 2007 |
Predecessor | Arapasowu I |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |