Ìwé-alàyé[ìdá]

Ọláníyì Mikail Àfọ̀njá, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sányẹ̀rì jẹ́ Òṣèré orí-ìtàgé, adẹ́rínpòṣónú, Olùgbéré jáde ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.[1]

Olaniyi Afonja a.k.a SANYERI
Ọjọ́ìbí14 Oṣù Kẹ̀wá 1974 (1974-10-14) (ọmọ ọdún 50)
Oyo State, Nigeria
IbùgbéIkeja
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor,Comedian
Olólùfẹ́Hawawu Omolara Afonja (m. 2013)
Àwọn ọmọ2, Boluwatife Afonja, Olasunkanmi Afonja

Ibẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Oláníyì Àfọ̀njá ní ìpìlẹ̀ Ọ̀yọ́, tí ó si jẹ́ akọ́bí ẹbí rẹ̀. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ St. Micheal ní Oke-Ìbò àti Ilé-ẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Girama Durbar ní ìpínlẹ̀ [Ọ̀yọ́]] kan náà.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Dolapo, Amodeni (13 December 2013). "Comic actor, Sanyeri denies using wedding to raise funds". Ecomium Weekly. http://www.encomium.ng/comic-actor-sanyeri-denies-using-wedding-to-raise-funds/. Retrieved 11 February 2016. 
  2. Bada, Gbenga (2018-11-08). "Sanyeri is the successful joker at 40". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-12-14.