Sílábọ́ọ́sì ( /ˈsɪləbə/; jẹ́ ìlapa-èrò iṣẹ́ [1]) tàbí àkóónú kókó iṣẹ́ inú ètò ẹ̀kọ́ kan tí a fẹ́ fi kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́. Kéré àti jẹ́ kí olùkọ ó ní ìkápá lórí ohun tí ó fẹ́ kọ́, kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà ó sìn lè gbaradi fún kókó ẹ̀kọ́ tó kan kí Won lè ṣe àṣeyege kẹ́yìn ẹ̀kọ́ náà. [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Merriam-Webster Dictionary <https://www.merriam-webster.com/dictionary/syllabus>
  2. "What does syllabus mean?". Definitions.net. 2020-02-07. Retrieved 2020-02-07.