Sùltánù ìlú Sókótó

(Àtúnjúwe láti Sùltánì ìlú Sókótó)

Sùltánù ìlú Sókótó tabi Sultani ilu Sokoto ni oruko oye Kalifu ilu Sokoto, ohun na lo si tun je baba agba fun awon musulumi ni Apaariwa Naijiria.

Sultani ori oye lowolow ni Muhammed Sa'adu Abubakar.