Súnkànmí Ọmọbọ́láńlé
Súnkànmí Ọmọbọ́láńlé (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1981) jẹ́ gbajúgbajà òṣèré àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ìlọrà ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Súnkànmí jẹ́ ọmọ bíbí inú gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Papi Luwe.[1][2]
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
àtúnṣeSúnkànmí bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà ni Nigerian Military School, nígbẹ̀yìn, ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ètò okoòwò ní Ifáfitì Ọlábísí Ọnàbáńjọ. Lọ́dún 2011, ó fẹ́ aya rẹ̀ tí ó ń jẹ́ Abímbọ́lá Bákàrè.[3] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò ni Súnkànmí tí darí tí ó sìn kópa.[4] [5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2014-06-22. Retrieved 2015-02-20.
- ↑ "Sunkanmi Omobolanle, Chika Agatha crash out Sexiest in Nollywood - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2013-08-17. http://www.vanguardngr.com/2013/08/sunkanmi-omobolanle-chika-agatha-crash-out-sexiest-in-nollywood/.
- ↑ "Meet 10 of the best Yoruba actors and their wives - Nigerian Entertainment Today". Nigerian Entertainment Today. 2016-05-03. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ Benitte (2016-04-07). "10 Things You Didn't Know About Sunkanmi Omobolanle". Youth Village Nigeria. Archived from the original on 2019-12-14. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ "5 things you probably don't know about actor". Pulse Nigeria. 2016-03-01. Archived from the original on 2019-12-14. Retrieved 2019-12-14.