STS-32 je iranlose 33k ninu eto Oko-Alobo Ofurufu ti NASA, ati igbera 9k fun Oko-Alobo Ofurufu Columbia. Nigba to gbera ni 9 January 1990, o je igba akoko leyin STS-61-C ti Pepe A ni Agbala 39 ti Gbongan Ofurufu Kennedy je lilo fun igbera; bakanna o tun je igba akoko ti Mobile Launcher Platform No. 3 (MLP-3) je lilo ninu eto Oko-Alobo Ofurufu. STS-32 lo je, nigbana, iranlose oko-alobo to pe julo to waye, pelu igba to to ojo 11. Ko to kan STS-32, iranlose kan soso to ni iye igba kanna ni STS-9 in 1983.

STS-32
Àmìyẹ́sí ìránlọṣe
Statistiki ìránlọṣe
Orúkọ ìránlọṣeSTS-32
Space shuttleColumbia
Launch pad39-A
Launch date9 January 1990, 7:35:00 am EST
Landing20 January 1990, 1:35:37 am PST, Edwards Air Force Base
Mission duration10 days, 21 hours, 36 seconds
Number of orbits172
Orbital altitude178 nautical miles (330 km; 205 mi)
Orbital inclination28.5 degrees
Distance traveled7,258,096 kilometres (4,509,972 mi)
Crew photo
Clockwise from top left: Ivins, Low, Dunbar, Wetherbee, Brandenstein.
Ìránlọṣe bíbátan
Ìránlọṣe kíkọjásẹ́yìn Ìránlọṣe kíkànníwájú
STS-33 STS-33 STS-36 STS-36