Sa'a Ibrahim jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti òṣìṣẹ́ ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tó máa di alága Broadcasting Organisation of Nigeria (BON). Òun sì ni olùdarí àgbà fún ẹ̀rọ̀-amóhùn máwòrán ti Abubakar Rimi.[1][2]

Ìgbésí ayé rẹ̀ àtúnṣe

Hajia Sa'a Ibrahim ni wọ́n bí sínú ìdílé Malam Ibrahim àti Yalwa Bello ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1960 ní Magashi Quarters ní ìjọba ìbílẹ̀ Gwale ní ipinle Kano .

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Sa'a Ibrahim elected new BON chairman, becomes first female to lead since 1988". Daily Nigerian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-23. Archived from the original on 2021-06-27. Retrieved 2021-06-29. 
  2. "Sa'a Ibrahim appointed MD of Kano TV". Retrieved 2021-07-02 – via PressReader.