Sabrina Draoui (tí wọ́n bí ní 24 Oṣù Kọkànlá, Ọdún 1977) jẹ́ olùdarí eré àti olùyàwòrán ọmọ orílẹ̀-èdè Àlgéríà.

Sabrina Draoui
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kọkànlá 1977 (1977-11-24) (ọmọ ọdún 47)
Batna, Algeria
Orílẹ̀-èdèAlgerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Science and Technology Houari Boumediene
Iṣẹ́Film director, photographer
Ìgbà iṣẹ́2008-present