Wọ́n bí Fọláṣadé Ọláyínká Bádérìnwá, tí wọ́n mọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ sí Ṣadé Bádérìnwá (/ˈʃɑːd ˈbɑːdərɪnwɑː/ /ˈʃɑːd ˈbɑːdərɪnwɑː/ SHAH-day BAH-dər-in-wah), ní ọjọ́ kẹrìnlá Oṣù kẹ́rin, 1969. (born April 14, 1969) jẹ́ olùdarí ètò ní orí  WABC ìkànì kéje (Channel 7). Bákan náà ni ó tún ṣe amúgbá-lẹ́gbẹ́ lórí ètò olósẹ̀-ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú Diana Williams tí ó ma ń wáyé ní dédé agogo márun ìrọ̀lẹ́ (Eyewitness News) àti ìròyìn alágo mọ́kànlá (11.pm news) kan pẹ̀lú Bill Ritter.

Sade Baderinwa
Ọjọ́ìbíFolasade Olayinka Baderinwa
Oṣù Kẹrin 14, 1969 (1969-04-14) (ọmọ ọdún 54)
Baltimore, Maryland
Iṣẹ́Journalist
Notable credit(s)Co-anchor of Eyewitness News at 5:00pm for WABC-TV (2003-present) with Diana Williams and the Co-anchor for "Eyewitness News at 11" (2011-present) with Bill Ritter.

Ṣade dara po mo ile ise WABC ni odun 2003 leyin ti o se nkan die ni ilu abinibi re Baltimore, Maryland, ni bi ti o ti dari eto iroyin lori WBAL-TV fun bi odun meta. Sade ropo Roz Abrams, ti o kuro nile ise yii ni odun 2003 lati gbase ni agogo marun si mokanla ale (5 and 11 p.m.) ni  WCBS-TV.[1]  Ni ojo ketadin-logun Osu keje, odun 2004 (July 23, 2004) nigba ti o n mura lati jabo isele omiyale ti o sele ni Hackensack, New Jersey , ni oloko kan gba ti o si salo (hit and run).[2][3][4] Sade pada sidi ise re (Eyewitness News on December 13, 2004). leyin opo ise abe ati ayewo igba-degba,  physical therapy,[5]

Bádérìnwá ni o je adeke osan tele ki wo to gbe lo si ago marun irole (5:p.m) pelu Diana Williams. Ṣadé han ninu The View  gege bi olugbalejo lori October 27, 2006. Bakan naa, ni Osu karun (May, 2011), Bádérìnwá di amugba-legbe iroyin alaago mokanla (11 p.m. news) pelu Bill Ritter, ti oun naa si n ropo Liz Cho, ti o kuro ni ipo adari fun iwe iroyin (new WABC 4 p.m newscast), eyi ti o fese mule leyin ti The Oprah Winfrey Show kase kuro nile tan ti Baderinwa si te siwaju lati ma ba eto iroyin alaago marun un 5 p.m. si 11 p.m. lọ.[6]

Baba re je Yoruba omo orile ede Naijria ti iya re si je omo ile German. Oruko re akoko ni  "Folasade", to tumo si "Someone who uses wealth as  crown".[7] O jade ni ile eko agba ti University of Maryland College Park.[8] Leyin ti iya re ti ja kale lati omode  ti enika ti o je  African American si gba to amo oun ati baba re to n be ni Naijiria n soro bakan.[9]

References àtúnṣe

  1. St. George, Donna (2006-10-31). "A Politician Who Thinks Like a Linebacker". Washington Post. pp. A01. https://www.washingtonpost.com/wp-dyn/content/article/2006/10/30/AR2006103001361.html. Retrieved 2006-12-03. 
  2. WABC-TV: Sade Baderinwa Update: Cops Hunt Driver, $5,000 Reward Offered Archived 2004-12-31 at the Wayback Machine.
  3. Huff, Richard; Hufte, Tom (2004-07-24). "Daily News: TV news anchor struck in hit-and-run". New York Daily News. Archived from the original on 2006-06-29. https://web.archive.org/web/20060629110701/http://www.nydailynews.com/front/story/215341p-185399c.html. Retrieved 2006-12-03. 
  4. "WBAL-TV: Sade Baderinwa talks about accident that nearly killed her". TheWBALChannel.com. 2005-02-24. Archived from the original on 2006-11-27. https://web.archive.org/web/20061127095454/http://www.thewbalchannel.com/entertainment/4227367/detail.html. Retrieved 2006-12-03. 
  5. Huff, Richard (2004-12-17). "Ch. 7 anchor's road to recovery". New York Daily News. Archived from the original on 2005-12-27. https://web.archive.org/web/20051227045952/http://www.nydailynews.com/entertainment/story/262757p-224977c.html. Retrieved 2006-12-03. 
  6. Huff, Richard (2011-04-22). "Inner Tube: Liz Cho, David Novarro to anchor 'Eyewitness News First at 4,' taking 'Oprah' timeslot". New York Daily News. http://www.nydailynews.com/entertainment/tv/2011/04/22/2011-04-22_inner_tube_liz_cho_david_novarro_to_anchor_eyewitness_news_first_at_4_taking_opr.html. Retrieved 2011-04-24. 
  7. Meaning of Folasade in Nigerian.name
  8. Biography at "Sade Baderinwa". WABC-TV. Archived from the original on 2007-02-12. https://web.archive.org/web/20070212045745/http://abclocal.go.com/wabc/story?section=bios&id=3301260. Retrieved 2007-04-08. 
  9. Stephanie Shapiro (May 12, 2002). "Anchor In Her Life". The Baltimore Sun. Archived from the original on 2011-12-10. https://web.archive.org/web/20111210151731/http://articles.baltimoresun.com/2002-05-12/news/0205130313_1_sade-baderinwa-house-anchor.