Sadio Mane
Sadio Mané tí wọ́n bí ní oṣù kẹrin ọdún 1992. Ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Senegal, ó tún jẹ́ agbábọ́ọ̀lù lọ́wọ́ iwájú fún ikọ̀ Bayern Munich nínú ìdíje Bundesliga. Ó tún gbajú-gbajà àti ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù tí ó dára jù lọ ní Ilẹ̀ Afrika. Wọ́n mọ̀ ọ́n fún eré-sísá, ègé-gígé lórí pápá.[4][note 1]
Sadio Mane N*10 du Senegal.jpg Mané with Senegal at the 2021 Africa Cup of Nations | |||
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 10 Oṣù Kẹrin 1992[1] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Bambali, Senegal | ||
Ìga | 1.74 m[2] | ||
Playing position | Forward, Winger[3] | ||
Club information | |||
Current club | Bayern Munich | ||
Number | 17 | ||
Youth career | |||
2009–2011 | Génération Foot | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2011 | Metz B | 12 | (2) |
2012 | Metz | 22 | (2) |
2012–2014 | Red Bull Salzburg | 63 | (31) |
2014–2016 | Southampton | 67 | (21) |
2016–2022 | Liverpool | 196 | (90) |
2022– | Bayern Munich | 20 | (6) |
National team‡ | |||
2012 | Senegal U23 | 4 | (0) |
2012– | Senegal | 95 | (35) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 15:25, 8 April 2023 (UTC). † Appearances (Goals). |
Mane bẹ̀ẹ̀rẹ ère bọ́ọ̀lu àfẹsẹ̀gbá pẹ̀lu ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Metz nínú ìdíje Ligue 2 tí ìlú France nígbà tí ó sì fi jẹ́ ọmọ ọdún ọkàn-dín-lógún. Ṣùgbọ́n ó kúrò nínú ikọ̀ náà tí ó sì dara pò mọ́ ikọ̀ Red Bull Salzburg ní ọdún 2012 pẹ̀lú Mílíọ̀nù mẹ́rin Euro, eléyìí tí ó sì ife ẹ̀yẹ àti kọ́ọ̀pù ẹsẹ̀ kùkú ní ọdún 2013-14. Lẹ́yìn ìgbà náà, Mane lọ sí ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Southampton tí ìlú England pẹ̀lú owó tí ó tó 11.8m Euro. Tí ó sì gbá àmì ẹ̀yẹ Fatest hatrick ní ìṣẹ́jú eerin dín lógo rìn nínú ìdíje náà, nígbà tí wọ́n ń kọjú ikọ̀ Aston Villa.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "FIFA Club World Cup Qatar 2019: List of Players: Liverpool FC" (PDF). FIFA. 5 December 2019. p. 7. Archived from the original (PDF) on 5 December 2019. Retrieved 17 January 2020.
- ↑ "Sadio Mané". FC Bayern Munich. Archived from the original on 1 July 2022. Retrieved 1 July 2022.
- ↑ "Sadio Mané FC Bayern München Player Profile Bundesliga". Bundesliga. 2023. Archived from the original on 5 December 2023. Retrieved 15 February 2023.
- ↑ Ajith, Shambhu. "Ranking the 10 best football players this year (2022)". www.sportskeeda.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-15.
- ↑ "The 100 best footballers in the world 2016 – interactive". The Guardian. 20 December 2016. https://www.theguardian.com/football/ng-interactive/2016/dec/20/the-100-best-footballers-in-the-world-2016-interactive.
- ↑ "The 100 best footballers in the world 2017". The Guardian. 19 December 2017. https://www.theguardian.com/football/ng-interactive/2017/dec/19/the-100-best-footballers-in-the-world-2017-interactive.
- ↑ "The 100 best male footballers in the world 2018". The Guardian. 20 December 2018. https://www.theguardian.com/football/ng-interactive/2018/dec/18/the-100-best-male-footballers-in-the-world-2018-nos-100-71.
- ↑ "The 100 best male footballers in the world 2019". The Guardian. 20 December 2019. https://www.theguardian.com/global/ng-interactive/2019/dec/17/the-100-best-male-footballers-in-the-world-2019.
- ↑ "The 100 best male footballers in the world 2020". The Guardian. 24 December 2020. https://www.theguardian.com/football/ng-interactive/2020/dec/21/the-100-best-male-footballers-in-the-world-2020.
- ↑ "The 100 best male footballers in the world 2021". The Guardian. 24 December 2021. https://www.theguardian.com/football/ng-interactive/2021/dec/21/the-100-best-male-footballers-in-the-world-2021.
- ↑ "The 100 best male footballers in the world 2022". The Guardian. 27 January 2023. https://www.theguardian.com/football/ng-interactive/2023/jan/24/the-100-best-male-footballers-in-the-world-2022.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/>
tag was found