Safia Abdul Rahman
Safia Abdul Rahman tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 1986 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin ti ilẹ̀ Ghana kan tí ó ń mú iwájú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana. Ó díje nínú ìdíje FIFA Women's World Cup ti ọdún 2007 . Ní ìpele ẹgbẹ́, ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [1]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Safia Abdul Rahman | ||
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kaàrún osù kaàrún ọdún 1986 | ||
Playing position | Iwájú | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | 0 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Canada - Ghana Match Report" (PDF). FIFA. Archived from the original (PDF) on December 23, 2014. Retrieved 22 February 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)