Saheed Balogun
Ìgbà iṣẹ́1978–presentNotable workÒfin mósèOlólùfẹ́
Saheed Balógun ni wọ̣́n bí ní ọjọ́ Karùún oṣu Kejì ọdún 1967 (February 5, 1967) ní ìpínlẹ̀ Kwara. Ó jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré jáde, adarí eré, àti olùṣe fíímù ilẹ̀ Nàìjíríà.
Saheed Balógun | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kejì 1967 Kwara State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Kwara State Polytechnic |
Iṣẹ́ |
|
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Saheed ní ìpínlẹ̀ Kwara tí ó jẹ́ (North Central Nigeria), ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Níbi tí ó ti kàwé alákọ̀ọ́ bẹ̀rẹ̀ , ìwé girama àti ilé ìwé gíga .[3] Ó kàwé jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ 'Kwara State Polytechnic' tí wọ́n ti yí padà sí (Kwara State University).[4] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1978, nígbà tí ó kọ́kọ́ ṣe ètò rẹ̀ kan lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán tí ó pè ní "Youth Today" lórí NTA.[5] Ó ṣe sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ 'City Girl' ní ọdún 1989, àmọ́ tí ó sì ti gbé ọ̀pọ̀ sinimá jáde tí ó sì tún ti ṣe adarí fún ọ̀pọ̀ eré orí-ìtàgé mìíràn rẹpẹtẹ.[6]
Àwọn ẹbí rẹ̀
àtúnṣeÓ fẹ́ ìyàwó rẹ̀ tí òun náà jẹ́ òṣèré orí ìtàgé ìyẹn Fathia Balogun ṣùgbọ́n wọ́n ti pínyà báyìí. Ó bí ọmọ ọkùnrin kan Khalid Balógun àti obìnrin kan Aliyah Balógun.[7]
Lára àwọn sinimá tó ti ṣe ni:
àtúnṣe- Modúpẹ́ Tèmi ( Thankful ) - The first two cast movie in Africa
- Gbogbo Èrè ( Total profit ) - The first three cast movie in west Africa
- Third Party - The first ever ankara movíe in Africa
- Òfin mósè (2006).
- Family on Fire (2011)
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ https://web.archive.org/web/20150218103942/http://www.punchng.com/entertainment/e-punch/yoruba-actors-not-under-any-spell-saheed-balogun/. Archived from the original on February 18, 2015. Retrieved February 16, 2015. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ https://web.archive.org/web/20150218103936/http://www.punchng.com/entertainment/saturday-beats/people-should-learn-from-my-past-marriage-saidi/. Archived from the original on February 18, 2015. Retrieved February 16, 2015. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ https://web.archive.org/web/20150216215221/http://www.thisdaylive.com/articles/saheed-balogun-talks-about-my-failed-marriage-distract-my-creativity/176553/. Archived from the original on February 16, 2015. Retrieved February 16, 2015. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ "Saheed Balogun: Talks About My Failed Marriage Distract My Creativity". Thisday. April 14, 2014. Archived from the original on February 16, 2015. Retrieved January 19, 2014.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Empty citation (help)