Saidat Adégòké tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1985 (24 September 1985) ní ìlú Ìlọrin, Ìpínlẹ̀ Kwara , lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin.[1]

Saidat Adégòké
Personal information
Ọjọ́ ìbí24 Oṣù Kẹ̀sán 1985 (1985-09-24) (ọmọ ọdún 39)
Ibi ọjọ́ibíÌlọrin , Ìpínlẹ̀ Kwara
Club information
Current clubLugano
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2011–2012FCF Como 2000
2008–2009Milan
National team
2010Nàìjíríà
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Iṣẹ́ rẹ̀ bí agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin

àtúnṣe

Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún ìkọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí Remo QueensNàìjíríà. Lẹ́yìn náà, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ACF Trento ní orílẹ̀ èdè Italy. Ó gbá bọ́ọ̀lù mẹ́ta sáwọ̀n fún ìkọ̀ rẹ̀ nínú ìfẹsẹ̀wọ̀nsẹ̀ mẹ́rìndínlógún. Lẹ́yìn èyí, ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ACF Milan lóṣù kẹjọ ọdún 2008.[2] In Milan she developed and by summer 2011, scored 19 goals in 52 games.[3] At the beginning of the season 2011/2012 she changed to FCF Como 2000.[4]

Iṣé rẹ̀ lókè-òkun

àtúnṣe

Láti ọdún 2010, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìkọ̀ agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá obìnrin tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[5]

Àwọn ìtọ́kasí ìta

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-women-footy-bio-stub

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe