Salah El-Din Ahmed Mourad Zulfikar (Lárúbáwá: صلاح ذو الفقار‎, Àdàkọ:IPA-arz; tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kìíní ọdún 1926 tí ó sì fi ayé silẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1993), jẹ́ Òṣeré àti olùṣe fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè Íjíbítì nígbà ayé rẹ̀.[1][2] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Íjíbítì, kí ó tó di òṣeré ní ọdún 1956. Ọ̀pọ̀ káà mọ́ ara àwọn òṣeré tí ó gbajúmò nínú ìtàn Íjíbítì.[3][4] Zulfikar kó ipa nínú eré tí ó tó ọgọ́rùn-ún láàrin ọdún mẹ́tàdínlógójì tí ó fi jẹ́ òṣeré kí ó tó fi ayé silẹ̀.[5]

Salah Zulfikar
ORE
Zulfikar, c. 1972
Orúkọ àbísọصلاح ذو الفقار
Ọjọ́ìbíSalah El-Din Ahmed Mourad Zulfikar
(1926-01-18)18 Oṣù Kínní 1926
El Mahalla El Kubra, Kingdom of Egypt
Aláìsí22 December 1993(1993-12-22) (ọmọ ọdún 67)
Zamalek, Cairo, Egypt
Orílẹ̀-èdèEgyptian
Orúkọ mírànÀdàkọ:Plain list
Iléẹ̀kọ́ gígaEgyptian Police Academy
Iṣẹ́
  • Police officer
  • actor
  • film producer
Ìgbà iṣẹ́1956–1993
Notable workFull list
Olólùfẹ́Àdàkọ:Plain list
Àwọn ọmọAhmedMona
Parents
ẸbíZulfikar family
Honours Order of the Republic - Grand Cordon
Fáìlì:Order of the Science and Arts - Grand Cordon BAR.jpg Order of Sciences and Arts
Executive director of the Afro-Asian People's Solidarity Organisation
In office
1957–1962
Founder and Chairman of Salah Zulfikar Films
In office
1962–1978
Deputy President of the Syndicate of Artists
In office
1986–1990
Àdàkọ:Infobox police officer

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Memory of the day: Birth anniversary of Salah Zulfikar". EgyptToday. 2021-01-18. Retrieved 2023-03-25. 
  2. "Top 100 Egyptian Films (CIFF)". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-31. 
  3. Kijamii. "11 Golden Age Egyptian Actors We Still Have A Crush On Today | NileFM | EGYPT'S#1 FOR HIT MUSIC". nilefm.com. Archived from the original on 14 November 2021. Retrieved 2021-10-01. 
  4. "Remembering Salah Zulficar - Film - Arts & Culture". Ahram Online. Retrieved 2021-10-01. 
  5. Ammar, Maya (2014-12-07). "8 Egyptian Actors from the 60s Who Stole Our Hearts". Scoop Empire (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-27.