Saleh Kebzabo
Saleh Kebzabo (Àdàkọ:Langx, tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1947 ní Léré, Chad)[1] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Chad. Òun ni ààrẹ National Union for Democracy and Renewal (UNDR) àti igbákejì ní Ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ti Chad.[2] Òun ni mínísítà àgbà orílẹ̀ ède Chad láti ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹwàá ọdún 2022.
Saleh Kebzabo | |
---|---|
صالح كبزابو | |
Kebzabo in 2016 | |
Prime Minister of Chad | |
In office 12 October 2022 – 1 January 2024 | |
Ààrẹ | Mahamat Déby |
Asíwájú | Albert Pahimi Padacké |
Arọ́pò | Succès Masra |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹta 1947 Léré, French Equatorial Africa (now Chad) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Union for Democracy and Renewal |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Présidentielle au Tchad: Qui sont ces 6 candidats ? Par E.T".
- ↑ "Saleh Kebzabo: "A voir Déby renforcer sa sécurité, circuler dans des véhicules blindés, changer d’itinéraire, dormir à des endroits différents, se montrer le moins possible en public, on se dit que plusieurs ressorts sont cassés et que, dans ces condition"", Alwihda, September 30, 2004 Àdàkọ:In lang. "<". Archived from the original on December 10, 2004. Retrieved 2017-12-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)