Salem Elmslaty
Salem Fathi Elmslaty (ti a bi ni ọjọ kankanlelogbon Oṣu Kẹwa Ọdun 1992), tl a le ko ati sipeli bi Salem Al-Musallati ati ti a mọ ni ibigbogbo bi Salem Roma, jẹ agbabọọlu Libyan kan ti o n gba bọọlu fun Al-Nasr gege agbabọọlu agbaowoiwajun .
Ise Oke'ere
àtúnṣe- Awọn ikun ati awọn abajade ṣe atokọ awọn ibi-afẹde Libya ni akọkọ.
Rara. | Ọjọ | Ibi isere | Alatako | O wole | Abajade | Idije |
---|---|---|---|---|---|---|
1. | Oṣu kọkanla ọjọ 17, ọdun 2018 | Stade Linité, Victoria, Seychelles | </img> Seychelles | 5-0 | 8–1 | 2019 Africa Cup of Nations afijẹẹri |
Awon Ife re
àtúnṣe- Al-Nasr
- 2016 Libyan Premier League ti o gba goolu mejo wọlé ti o si fi gba eniti o gba goolu ti o poju lo.