Samara Weaving
Samara Weaving (tí a bí ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kejì ọdún 1992) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Austrilia. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré rẹ̀ nípa kíkó ipa Kirsten Mulroney nínú Out of the Blue (2008). Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó kó ipa Indi Walker nínú eré Home and Away (2009–2013), èyí tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Australian Academy of Cinema and Television Arts (AACTA) fún ni ẹ̀ka obìnrin.
Samara Weaving | |
---|---|
Weaving ní ọdún 2015 | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Kejì 1992 Adelaide, South Australia, Australia |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2005– ìsinsìnyí |
Olólùfẹ́ | Jimmy Warden (m. 2019) [1] |
Àwọn olùbátan |
|
Láàrin ọdún 2015 sí ọdún 2023, ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, àwọn eré bi Ash vs Evil Dead (2015–2016) àti SMILF (2017–2019). Ní ọdún 2017, ó tún ṣeré nínú àwọn fíìmù bi Mayhem, The Babysitter, àti Three Billboards Outside Ebbing, Missouri, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ a Screen Actors Guild Award fún ipa rẹ̀ nínú fún Three Billboards Outside Ebbing.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedONeill