Samke Makhoba

Samkelisiwe "Samke" Makhoba (tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n ọdún 1989) jẹ́ òṣèré Gusu Afirika tí ó kópa nínú eré Shuga èyí tí MTV gbé kalẹ̀.[1]

Samkelisiwe Makhoba
Samke Makhoba plays Khensani in MTV Shuga Down South.png
Samke Makhoba
Ọjọ́ìbí25 Oṣù Kẹfà 1989 (1989-06-25) (ọmọ ọdún 32)
Umlazi,KwaZulu-Natal,South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African
Ẹ̀kọ́University of the Western Cape
University of Witwatersrand
Iṣẹ́actress
EmployerMTV Shuga

Ìgbésí ayéÀtúnṣe

Wọ́n bí Makhoba sí ìlú Umlazi ní ọdún 1989. Ó kọ́kọ́ yàn láti kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ Science ní Ilé- ẹ̀kọ́ gíga ti University of Western Cape ṣùgbọ́n ó yípadà láti kẹ́kọ̀ọ́ Fiimu & Tẹlifísíọ̀nù ní Ilé- ẹ̀kọ́ gíga ti University of Witwatersrand[2]

 
Khensani lori MTV Shuga Down South ní oṣù Kìíní ọdún 2019

Awọ̀n ìtọ́kàsiÀtúnṣe

  1. "Meet the cast of MTV Shuga Down South". ZAlebs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-02-22. Retrieved 2019-02-22.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Samke Makhoba | TVSA". www.tvsa.co.za. Archived from the original on 2019-02-23. Retrieved 2019-02-22.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)