Samuel Adams

Olóṣèlú

Wọ́n bí Adams ní ọdún 1722. Ó kú ní 1803. Olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Àmẹ́ríkà ni tí ó ń fẹ́ kí àyípadà wa. Boston ni wọ́n ti bí i. Láti nǹkan bíi 1765 ni ó ti ń sọ pé ẹni tí kò bá ní aṣojú kò gbọdọ̀ san owó-orí (no taxation without representation). Ó gbé ‘Boston tea-party’ ga. Ní 1776, ó fi ọwọ́ sí ìwé òmìnira (declaration of independent).

Samuel Adams
In this 1772 portrait by John Singleton Copley, Adams points at the Massachusetts Charter, which he viewed as a constitution that protected the peoples' rights.[1]
4th Governor of Massachusetts
In office
October 8, 1793 – June 2, 1797
LieutenantMoses Gill
3rd Lieutenant Governor of Massachusetts
In office
1789–1793
GómìnàJohn Hancock
President of the Massachusetts Senate
In office
1782 – 1785
1787–1788
Delegate from Massachusetts to the Continental Congress
In office
1774–1781
Clerk of the Massachusetts House of Representatives
In office
1766–1774
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíSeptember 27 [O.S. September 16] 1722
Boston, Massachusetts
AláìsíOctober 2, 1803(1803-10-02) (ọmọ ọdún 81)
Boston, Massachusetts
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic-Republican (1790s)
(Àwọn) olólùfẹ́Elizabeth Checkley,
Elizabeth Wells
Signature


  1. Alexander, Revolutionary Politician, 103, 136; Maier, Old Revolutionaries, 41–42.
  2. Wells, Life and Public Services, 2:221.