Oba Samuel Odulana Odugade I (ojoibi 20 October, 1920) ni Olubadan ogoji lowolowo ni ilu Ibadan. O gun ori ite ni 2007. O ropo Oba Yunusa Ogundipe, Arapasowu 1.

Samuel Odulana Odugade I
Olubadan
Coronation 7 Osu Karun, 2007
Predecessor Arapasowu IItokasiÀtúnṣe