Samuel Okwaraji

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Samuel Sochukwuma Okwaraji (19 May 1964 – 12 August 1989) je oni-ise agbaboolu-elese to gba boolu fun Naijiria. O tun je agbejoro lori ofin ibasepo awon orile-ede lati Pontifical Lateran University ilu Romu.[1] O ku nigba to wo lule nitori idina inu okan-aya to ba ni iseju 77k ere boolu ikopa ninu Ife-Eye Agbaye pelu Angola ni Papa Isere National ni Surulere, Lagos State ni ojo 12 osu kejo odun 1989.

Samuel Okwaraji
Personal information
OrúkọSamuel Sochukwuma Okwaraji
Ọjọ́ ìbí(1964-05-19)19 Oṣù Kàrún 1964
Ibi ọjọ́ibíOrlu, Nigeria
Ọjọ́ aláìsí12 August 1989(1989-08-12) (ọmọ ọdún 25)
Ibi ọjọ́aláìsíLagos, Nigeria
Playing positionMidfielder
Youth career
1984–1985AS Roma
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1985–1986Dinamo Zagreb1(0)
1986–1987Austria Klagenfurt?(?)
1987–1989VfB Stuttgart0(0)
1987–1988SSV Ulm (loan)28(5)
National team
1988–1989Nigeria8(1)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).


  1. Okwaraji comes alive in Abuja Archived 2011-07-07 at the Wayback Machine. at African Soccer Union.


Àdàkọ:Nigeria Squad 1988 Summer Olympics