Samuel Peter
Samuel Okon Peter tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Karùn-ún oṣù kẹsàn-án ọdún 1980 (September 5, 1980 ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà), tí orúkọ ni ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ "The Nigerian Nightmare," jẹ́ eléré ìdárayá ajẹ̀ṣẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríàtí ó jẹ́ ajẹ̀ṣẹ̀-àgbà àti olùborí ajẹ̀ṣẹ̀-àgbà àgbáyé WBC nígbà kan rí.
Statistics | |
---|---|
Real name | Samuel Okon Peter |
Nickname(s) | The Nigerian Nightmare |
Rated at | Heavyweight |
Height | 6 ft 1 in (1.85 m) |
Nationality | Nigerian |
Birth date | 5 Oṣù Kẹ̀sán 1980 |
Birth place | Akwa Ibom, Nigeria |
Stance | Orthodox |
Boxing record | |
Total fights | 36 |
Wins | 33 |
Wins by KO | 26 |
Losses | 3 |
Draws | 0 |
No contests | 0 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |