Samuel obi
Samuel Onyeka Obi (1961/2 – ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin ọdún 2020) jẹ́ olóṣèlú àti òṣeré ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà ayé rẹ̀. Òun ni asọ̀rọ̀ fún ilé ìgbìmọ̀ asofin Ìpínlẹ̀ Delta, òun sì ni ó di ipò gomina Ìpínlẹ̀ Delta mú láàrin ọdún 2010 sí 2011. Títí di ìgbà ikú rẹ̀, òun ni olùṣọ́ àgùntàn àgbà ti ìjọ Oracle of God Ministry, Asaba, Ìpínlẹ̀ Delta.
Sam Obi | |
---|---|
Member representing Ika North East constituency in Delta State house of assembly | |
In office 2003–2015 | |
10th Speaker of Delta State house of assembly | |
In office 29 July 2010 – 7 June 2011 | |
Asíwájú | Martin Okonta |
Arọ́pò | Victor Ochei |
Governor of Delta State | |
In office 10 November 2010 – 10 January 2011 | |
Asíwájú | Emmanuel Uduaghan |
Arọ́pò | Emmanuel Uduaghan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Samuel Onyeka Obi Àdàkọ:Birth based on age as of date |
Aláìsí | (ọmọ ọdún 59) Asaba, Delta State, Nigeria |
Cause of death | Undisclosed illness |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Occupation |
|
Nípa ayé rẹ̀
àtúnṣeObi wá láti Ibiegwa quarters, Ute-Okpu, Ika North East, Ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ọba àti ọmọ ìdílé Ute-Okpu royal family. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀, HRM Obi Solomon Chukwuka I ni Obi ìlú Ute-Okpu lọ́wọ́ lọ́wọ́.[1]
Ikú rẹ̀
àtúnṣeObi fi ayé sílẹ̀ ní ilé rẹ̀ ní ìlú Asaba ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin ọdún 2021, èyí ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn àìsàn rán pé tí ó ṣe.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Ute-Okpu monarch expresses concern over youths' lack of respect for elders". The Nation Newspaper. 10 April 2015. Retrieved 7 April 2021.
- ↑ Odunsi, Wale (4 April 2021). "Sam Obi, ex-Delta acting governor is dead". Daily Post Nigeria. https://dailypost.ng/2021/04/04/sam-obi-ex-delta-acting-governor-is-dead.