Aboubakar Sangoulé Lamizana (January 31, 1916 – 26 May 2005) je Aare ati Alakoso Agba orile-ede Burkina Faso (nigba to je Upper Volta) tele.