Santiago Derqui
Santiago Rafael Luis Manuel José María Derqui Rodríguez (Córdoba June 21, 1809 – November 5, 1867) je Aare orile-ede Argentina tele.
Santiago Derqui | |
---|---|
4th Aarẹ orile-èdè Argentina | |
In office March 5, 1860 – November 4, 1861 | |
Vice President | Juan E. Pedernera |
Asíwájú | Justo José de Urquiza |
Arọ́pò | Juan E. Pedernera |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Córdoba | Oṣù Kẹfà 21, 1809
Aláìsí | November 5, 1867 Corrientes | (ọmọ ọdún 58)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentine |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Federalist |
Ìgbésíayé
àtúnṣeÀkọ́bíkunrin Manuel José María Derqui y Garcia ati ìyàwó rè Ramona Rodriguez y Ordun̄a, Santiago Derqui kàwé ni Córdoba National University, ó gba àmì ẹyẹ nínú fásitì na agbejoro ni ọdún 1831. Ni ojó kẹrinla oṣù kàrún, ọdún 1845, ó fẹ́ Modesta García de Cossio y Vedoya García (1825–1885) tí o si bi ọmọkunrin méta fún (Manuel Santiago, Simón, and Santiago Martín Antonio) ati ọmọbìnrin méta (Josefa, Justa Dolores Belisaria, and María del Carmen Modesta Leonor).
Ohun ni oluranlowo àkọ́kọ́ ati mínísítà ìjọba ti Corrientes Province lábẹ José María Paz. Justo José de Urquiza fún ni 'Business administrator' tí o si ran lọ sí Paraguay fún iṣẹ ilu orile-èdè miran.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Masones Ilustres Argentinos". Archived from the original on 2013-09-22. Retrieved 2013-04-02.