Sarah Àdegoke
Sarah Adegoke ni elere tennis lobinrin ni orilẹ ede Naigiria ti a bini ọdun 1997 ti o si dagba si ibadan nibi ti o sì kọ tennis lati ọwọ baba rẹ, Ọgbẹni Adegoke Adedapọ. Arabirinin naa ni ẹni ti a rank ju ninu elere tennis lobinrin ni orilẹ ede Naigiria[1].
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Keje 1997 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (double–handed backhand) |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 1–8 (WTA) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 1–10 (WTA) |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 874 |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 884(2019) |
Last updated on: 06 March 2019. |
Aṣeyọri
àtúnṣeItọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.celebsagewiki.com/sarah-adegoke
- ↑ https://twmagazine.net/news/events/meet-sarah-adegoke-the-first-lady-of-tennis/
- ↑ https://dailytrust.com/amp/nigerian-tennis-stars-say-year-2014-is-eventful
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-23. Retrieved 2022-05-23.