Sarah Ssentongo Kisawuzi jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Uganda tí ó gbajúmọ̀ fún ipá tí ó kó nínú eré Deception gẹ́gẹ́ bí Nalweyiso.[1][2][3][4]

Sarah Kisawuzi
Ọjọ́ìbíSarah Ssentongo
11 Oṣù Kọkànlá 1948 (1948-11-11) (ọmọ ọdún 76)
Ọmọ orílẹ̀-èdèUgandan
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2013–present
AwardsFull list

Iṣẹ́

àtúnṣe

Kisawuzi di gbajúmọ̀ fún ipa Nalweyiso tí ó kó nínú eré Deception láti ọdún 2013 di 2016. Ó gba àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tó dára jù lọ fún ipa tí ó kó nínú eré náà láti ọ̀dọ̀ Uganda Entertainment Awards ní ọdún 2015. Ó kópa nínú eré Queen of Katwe ní ọdún 2016. Ní ọdún 2019, ó kó ipa Mama Stella nínú eré Bed of Thorns àti ipa Barbara Batte nínú eré Power of Legacy.[5][6]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe

àtúnṣe
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó
2019 Bed of Thorns Mama Stella
Power of Legacy Barbara Batte
2016 Queen of Katwe Katende’s Grandmother
Second Chance
2013 Deception Nalweyiso
2012 Smart Attempt
2011 Where We Belong[7]
2009 Because of You
Hearts in Pieces

Àmì Ẹ̀yẹ

àtúnṣe
Ọdún Nominated work Association Category Esi
2016 Deception Uganda Film Festival Awards Best Actress in a TV Drama Yàán
2015 Uganda Entertainment Awards Best Actress Gbàá

Àwọn Ìtọ́kàsi

àtúnṣe