Sarah Ogoke (tí a bí ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1990) jẹ́ agbá bọ̀ọ́lù ọwọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amerika fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Ferroviário de Maputo àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù owó orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Sarah Ogoke
No. 8 – Ferroviário de Maputo
PositionShooting guard
LeagueFIBAACCW
Personal information
Born25 Oṣù Kẹfà 1990 (1990-06-25) (ọmọ ọdún 34)
The Bronx, United States
NationalityAmerican / Nigerian
Listed height1.75 m (5 ft 9 in)
Career information
CollegeSouthern Polytechnic State (2014)
NBA draft2014 / Undrafted

Ó kópa ní eré ijíde ti àwọn elégbé rẹ̀ obìnrin tí ó wáyé ní odún 2017 àti 2019.[2] Ogoke jé ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ agbá bọ̀ọ́lù ọwọ́ àwọn ọbìnrin tí a mọ̀ sí, D'tigress nígbà tí wọ́n kópa ní ìdíje bọ́ọ̀lù owó World Cup FIBA fún àwọn obìnrin ní ọdún 2018, ìdíje náà wáyé ní Tenerife, Canary Islands, Spain.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. FIBA profile
  2. 2017 Women's Afrobasket profile