Sir Thomas Sean Connery (25 Oṣù Kẹjọ 1930 - 31 Oṣù Kẹ̀wá 2020) je osere ati atokun filmu ara Skotlandi je osere to gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún Òṣeré Okùnrin Dídárajùlọ 2k lekan, Ebun BAFTA lemeji ati Wura Roboto lemeta.

Sir Sean Connery
Sean Connery, 2008
Ọjọ́ìbíThomas Sean Connery
25 Oṣù Kẹjọ 1930 (1930-08-25) (ọmọ ọdún 94)
Edinburgh, Scotland, UK
Aláìsí31 October 2020(2020-10-31) (ọmọ ọdún 90)
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1954-2006, 2010[1]
Olólùfẹ́Diane Cilento (1962-1973)
Micheline Roquebrune (1975-present)
Websitehttp://www.seanconnery.com