Segun Akeem Salawu jẹ́ olùkọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfíríkà. Ó gba oyè ọ̀mọ̀wé ní ọdún 2006 lẹ́yìn tí ó kọ àpilẹ̀kọ lórí Yorùbá àti oko Osanyen. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ni ó ti ṣe lórí èdè Yorùbá. [1]

Segun Akeem Salawu


Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "About Segun Akeem Salawu: - Biography, Facts, Career, Wiki, Life". peoplepill.com. 2020-03-23. Retrieved 2021-07-26.