Ṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí

(Àtúnjúwe láti Segun Odegbami)

Patrick Olúṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí tàbí Ṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1952 (August 27, 1952) jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ipò iwájú agbábọ́ọ̀lù sáwọ̀n ni ó máa ń gbá.[1] [2] [3] [4] Lọ́dún 2015, ṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí dára pọ̀ mọ́ Òṣèlú, ó sìn díje dupò Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn lọ́dún 2019, ṣùgbọ́n ìbò abẹ́lé kò gbè é. [5]

Segun Odegbami
Personal information
OrúkọPatrick Olusegun Odegbami
Ọjọ́ ìbí27 Oṣù Kẹjọ 1952 (1952-08-27) (ọmọ ọdún 72)
Ibi ọjọ́ibíAbeokuta, Nigeria
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1970–1984Shooting Stars-(-)
National team
1976–1982Nigeria46(23)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).



  1. Àdàkọ:NFT player
  2. "Segun Odegbami biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 1952-08-27. Retrieved 2020-01-09. 
  3. "Segun Odegbami". Transfermarkt (in Èdè Jámánì). Retrieved 2020-01-09. 
  4. "Segun Odegbami Bio, Stats, and Results". Olympics at Sports-Reference.com. 2017-12-18. Retrieved 2020-01-09. 
  5. Published (2015-12-15). "2019: Segun Odegbami declares Ogun gov bid". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-09.