Segun Toyin Dawodu
Segun Toyin Dawodu (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 13 oṣù October, ọdún 1960) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiriató sì jẹ́ oníṣègùn àrùn-ọpọlọ àti agbẹjọ́rò pẹ̀lú WellSpan Health. Ó ṣịṣẹ́ bí i ọ̀jọ̀gbọ́n pẹ̀lú Albany Medical College.[2][3]
Segun Toyin Dawodu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Segun Toyin Dawodu 13 Oṣù Kẹ̀wá 1960 Ijebu Igbo, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | America |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan University of London, Reuben College, Oxford-University of Oxford, King's College London, Johns Hopkins University, Northwestern University, George Mason University-Antonin Scalia Law School. |
Iṣẹ́ | Physician and Attorney |
Gbajúmọ̀ fún | Physician |
Olólùfẹ́ | Egbe Osifo-Dawodu[1] |
Website | dawodu.com |
Awọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "MedAccess Board". Retrieved 2022-05-17.
- ↑ Sanusi, Sola (2019-07-30). "Segun Toyin Dawodu specialises in pain and sports medicine in US, also a lawyer". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-28.
- ↑ Sanusi, Sola (2019-07-30). "Segun Toyin Dawodu specialises in pain and sports medicine in US, also a lawyer". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-07.