Sekinat Adesanya
Sekinat Adesanya Akinpelu (tí wọ́n bí ní 25 July 1987) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó máa ń kópa nínú eré sísá, fún irinwó mítà.[1]
Ìdíje rẹ̀ tó dára jù ni èyí tó parí eré náà, láàárín ìṣẹ́jú àáyá 52.48, tó wáyé ní ìdíje 2006 World Junior Championships.[2]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
àtúnṣeRepresenting Nàìjíríà | |||||
---|---|---|---|---|---|
2006 | World Junior Championships | Beijing, China | 6th | 400 m | 52.71 |
2nd | 4 × 400 m relay | 3:30.84 AJR | |||
2007 | All-Africa Games | Algiers, Algeria | 1st | 4 × 400 m relay | 3:29.74 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Sekinat ADESANYA". worldathletics.org. 1996-01-01. Retrieved 2024-04-11.
- ↑ "Athletics Podium". Athletics Podium. Retrieved 2024-04-11.