Sellapan Ramanathan
S. R. Nathan செல்லப்பன் ராமநாதன் | |
---|---|
6th President of Singapore | |
In office 1 September 1999 – 31 August 2011 | |
Alákóso Àgbà | Goh Chok Tong Lee Hsien Loong |
Asíwájú | Ong Teng Cheong |
Arọ́pò | Tony Tan Keng Yam |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Keje 1924 Singapore |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Singaporean |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Urmila Umi Nandey |
Alma mater | University of Malaya |
Profession | Civil servant |
Sellapan Ramanathan[1] (Àdàkọ:Indic; ojoibi 3 July 1924) je oloselu are Singapore to je Aare ile Singapore kefa. O gbajumo bi S. R. Nathan, o koko je biburafun ni September 1, 1999. Ni 1999 ati 2005, o je didiboyan bi Aare lisi alatako. Ni 2009, o koja Benjamin Sheares lati Aare ile Singapore to pejulo lori ipo. Igba re pari ni August 31, 2011.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Yap, Sonny; Lim, Richard; Leong, Weng Kam (2009). Men In White - The Untold Story of Singapore's Ruling Political Party, p.145. Singapore Press Holdings Ltd., Singapore, ISBN 9789814266246