Sẹ̀mítíìkì

(Àtúnjúwe láti Semitiiki (Semitic))

Semitic

Semitiiki

Semitic ni àwọn ènìyàn ka ju ti o ṣi ye wọn jù síbẹ̀ àwọn èdè kan wa ti wọn kò mọ rárá nipá ṣiṣe arópò extant ati extinet kan. Semitic ṣe ipatẹ adọọfa lorisiirisi. Nípa ìṣàkóṣo ti ìbílẹ̀ wọn ṣùgbọ́n dọsini kan àbọ̀ lo wà lábẹ́ ìṣàkóṣo àwọn Arabiki, ṣùgbọ́n àwọn kan rò wípé ko ba ojú mu lati ṣe bẹ. Àwọn Oludari kan gba pe Semitic a le ri orukọ wọn ni àríwá ìlà Oòrùn, àríwá Iwọ Òòrun àti Guṣu lábẹ́ ipin ẹka ìdílé kan ṣùgbọ́n aríyanjiyan wa lórí pe bóyá Arabiki wa ni ariwa ìlà Oòrun tàbí pẹ̀lú ẹ̀ka ìdílé Gúṣù. Arákùnrin tí Orúkọ rẹ̀ ń jẹ Hetzron (1972: 15-16)5 ṣe àríyànjiyàn lórí ipò

(1) Ẹka ìdílé àríwá ila Òòrun wa láti Akkadian, nítorí èdè to ti paré tó jẹ́ ayé òlàjú tó ti kọjá lọ ti àwọn Assyrians àti Babylonians nígbà to ṣi jẹ pé Akkadian wà ní lílò fún nǹkan bi Ọdún meji miliniọnu títí di àkókò ayé jésù Hetzron pin àríwá ìwọ̀ Oòrùn Semitiki si àringbùngbùn àti Gúṣù àríwá ṣi ẹ̀ka. Ti àwọn Ìsáájú dúró fún Aramaic ní àṣìkò ìgbà ayé àtijọ́ ati tí ode òní orisiirisi Aramaic ni wọ́n ń ṣọ lati nǹkan bí Centiuri mẹwa BC. Ṣẹ́yìn. nǹkan bì Centiuri mẹ́fà sẹ́yìn àwọn kirisitẹni Aramaic nìkan ní ó jẹ́ èdè to gbalè nígbà náà bi ó tilẹ̀ jẹ pé àwọn èdè tí á ń ṣọ ni ìlètò ti tàn Kariaye ìwọ̀ Òòrùn Aramaic /ma’lula(15) Turoyo (70) èdè tí á ń pe láàrín àwọn Olùṣo èdè ní Assyrian (200).


2. Ẹka arìngbùngbùn Guṣu ní èyà Canani tí a pín ti ó dúró fún èdè to tí parẹ́ legbẹ èdè ìlà Òòrun gẹ́gẹ́ bi Phonecian ati (Biblical) Hebrew. Àwọn phonecian, ni tòótó wọn ń sọ̀rọ̀ nipa Lebanon, nígbà to yá o ń tàn ká nípa gbígba Òmìnira, nígbà to ya ó di èdè àwọn keteji (Carthage) níbi tí á tí mọ hàn-án bí puniki. Èdè ìgbàlódé ti àwọn Hébérù ń ṣọ ni Isrealis lo ṣe àtúnṣe rẹ (4, 510). Èdè tí àwọn Ras Shamra àti Uguritic ń sọ kàyéfì lo jẹ́. Èdè to ti pẹ́ tí àwọn Quran ń lò láti Centiuri kẹrin AD, lo wà ṣùgbọ́n nígbà tó yá wọ́n padà ṣí tí Centiuri karun BC; ṣùgbọ́n síbẹ̀ wọ́n ko ṣọ mọ́. Loni Orísìírìsí ìpínlẹ̀ Arábìkì tí wọ́n ń so ní tí gbogbogbo ní àrín ìlà Òòrùn àti àríwá adúláwọ̀ Afíríkà. Ní Áfíríkà àwọn èdè tó hàn gbegedé wọn ṣi pegedé Egyptian (42,500), hassaniya (2, 230), ti wọn ń ṣọ ní Mauritania àti díẹ̀ lápá Mali Senegal àti Niger, Morocan (19,542); Shua (1,031), wọn ń ṣọ díẹ̀ ní Chad, Cameroon, Nigeria Niger; Sudanese (16,000-19,000) ohun nìkan ni wọ́n ń sọ ní Àríwá Sudan ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn Olùṣọ èdè ni Egypt àti Eritrea; Algerian Colloquial (22,400), tì wọ́n ń sọ Tunisia; àti Sulaimitoan (4,500) ṣùgbọ́n wọ́n ń ṣọ èdè yìí díẹ̀ ní Libya àti Egypt. Ó dá hàn yàtọ̀ ṣí ẹ̀dá ọ̀rọ̀ aláwomọ èdè oni ti Arabiki ṣùgbọ́n èdè Arabiki ní a ń lò fún ẹ̀kọ́ Ìṣàkóṣo àti Ìgbòòrò Ìbánisòrọ̀ bakan náà a ń lo gẹ́gẹ́ bi èdè kejì ó si jẹ́ èdè ìpìnlẹ̀ àkọ́kọ fún èdè Arábìkì. Ìyàtọ̀ ẹ̀dá Ìgbẹ́dègbẹ́yọ̀ wúni lórí nítorípé àpèjúwe àkọ́kọ́ Ferguson (1959) Maltese (330) wọn ń sọ̀rọ̀ nìpa ilè ti omi yíká ti Malta ati níbikíbi ohun ní ìpìlẹ̀ èdá ti Àríwá Afíríkà Arabiki ṣùgbọ́n tí ó tí tàn ka láàrín àwọn Italiàni.


(3) Sémítìkì to wa ní Guṣu kún fún àwọn Arabiki Guṣu àti Ethic Semitic Ṣùgbọ́n àwọn ti tẹ́lẹ̀ kún fún Orísìíríṣí bi Hadrami Mineah Ontabanian ati Sebaean, Òhun nìkan ni a mọ̀ láti ìwọ̀ Òòrùn Guṣu Arábìkì àkọsílè rè tí wà láti Centiuri méjọ BC pẹ̀lú Arábìkì ti Guṣu Soqotri (70), Mehri (77), Jibbali (25) àti Harsusi (700) Ṣùgbọ́n ki i se gbogbo àwọn Òmòwé to gboye nínú koko isẹ kan lo fara mọ̀. Ethic-Semitic kún fún àwọn ará Àríwá Eghiopic àti ẹ̀ka ọ̀rọ̀ aláwòmọ́ àti Liturgical G I’ IZ Ùqre (683) àti Tigrinya (6, 060) àti Ethiopia tí ó wa ní ẹ̀ka Guṣu to wa láàrin ita tì kò sí ní pínpín. Amharic (20, 000) èdè Ethopia jẹ tí gbogbo gbo ó wà lára ti tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Harari (26), O jé ẹni ti ahọ́n rẹ̀ fanimọ́ra tí ó si jẹ tí ìbìlẹ̀ ṣi gbogbo ìlú Harari gbogbo àwọn ẹgbẹ́ atòdefimọ̀ gbárajọ pẹ̀lú àwọn ará Àrìwá tí Gurage l’orisiirisi gẹ́gẹ́ bí Soddo (104) yàtọ̀ si tí àringbùngbùn tí ìwọ̀ Òòrùn pẹ̀lú Chaha, Masqan, e.t.c. tí wọ́n jẹ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ (1,856) Orísìírírìsí nǹkan tí Gurage fi kun ni silti (493) a ṣi ṣe àpínsowoó rẹ̀ ṣi ẹgbé èyí ti o wa láàrín. Ó ṣe pàtàkì kí á ka “Gurage” ká á ṣi fi hàn gẹ́gẹ́ bi èdè kan.